Review Ministries
Review series Episodes(Review Ministries)
Having a new life in Christ and taking your relationship with Him one day at a time, to the next level.....Please note: ALL Review Ministries Works ARE NOT MONETIZED! Free to access by allNote: Review Ministries Gives Credit For All Music Played During Every Cast(Which Includes The Writers/Composers, Producers, etc). Thank You For The Labour Of Love.
Author
Review Ministries
Category
Podcast website
Latest episode
Mar 30, 2025
Where to listen?
Podcasts in the app Replaio Radio Coming soonPodcasts are coming to the app soon. Install now and be the first to see a whole new take on podcasts
Episodes
Itoni Atokewa{¡¡} {Olori Ogun} 05.02.2023 19:29
L'ati oni, a o bere si wo apeere itoni Olorun fun awon/awa eniyan re nigba ti a ba se aapon lati wa oju re ninu awon igbese wa gbogbo. A o si bere ninu iwe Josua 6:1-7....👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻
Boundaries{¡} 04.02.2023 18:57
What is a boundary/what are they? Why are they set/put in place? What happens when we break them? Join us this morning as we start this series by looking at the very first boundary put in place/built by God in Genesis 2:9,15-17....and more..👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👨💻
Itoni Atokewa{¡} 29.01.2023 16:17
Owe 16:1-3,9.....d'arapo mo wa fun ibere eko onipele titun yi lati jo ko awon ohun ti o ye, ti o si to ki a se l'ori awon abaa, ero ohun igbese wa fun awon ose ati osu ti o wa niwaju lodun yi......👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👨💻👨💻👩💻👨💻.....
Fragrance Of Christ {¡¡¡} 28.01.2023 18:07
Join us as we bring this series to a close by looking at how the apostle Paul described the believer as the "representative" of Christ in 2 Corinthians 2:14-16....Do you truly represent Christ?🤔.....👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻
Awon Ireti Ati Ipongbe Okan Re{¡¡}{Ohun Titun} 22.01.2023 18:18
Isaiah 42:9, 43:18&19....kini awa bi onigbagbo ni lati se ni ireti ati ipongbe awon ohun titun ti Olorun se ileri re fun wa? D'arapo mo wa ka jo ko eko ti oni pelu apeere to toka re ninu bibeli 👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👩💻👩💻👨💻👩💻👩💻......
Fragrance Of Christ {¡¡} 21.01.2023 17:44
Romans 13:14 tells us to; "...clothe ourselves with the presence of the lord Jesus Christ".....How exactly can we do this and thereby spread the pleasant smell of Christ?🤔.....join us and let's study together....👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻
Awon Ireti Ati Ipongbe Okan Re{¡} 15.01.2023 19:00
Kini ireti ati ipongbe okan re l'ori ipo ti o wa lowolowo tabi ti o yi o ka? Kini ijaya/ipaya re paapaa julo ninu odun titun yi? D'arapo mo wa lati bere eko akoko fun odun yi gege bi emi Olorun ti fi si wa l'okan ki o le mo bi o ti d'oju ija ko ota lori awon ero asan ati ireti odi...👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻.....
Fragrance Of Christ {¡} 14.01.2023 16:12
Join us this morning as we start our first series for the year and let's study about what the fragrance of Christ means and how it can be spread. We'll start by reading from the book of Acts👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻.....
Eto Review Pataki Fun Idupe Odun 08.01.2023 17:40
D'arapo mo wa fun eto pataki fun ijosin ati fifi adura bere odun titun 2023.....E kaabo pada si ori eto review!🙏🙏🎸🥁🎻🎺🎷🎵🎶🙏🙏...
New Year Thanksgiving (Prayers) 07.01.2023 22:15
Join us on this special episode to give thanks to the lord for safe arrival into the new year and also to commit the year unto Him.....Welcome Back!🙏🙏🎸🥁🎻🎺🎷🎵🎶🎶🙏🙏.....
Itilebosile/Atilebosile {¡¡}: Eto Pataki Fun Odun Keresimesi 25.12.2022 17:01
D'arapo mo wa lowuro keresimesi yi ki a jo ko nipa atilebosile Jesu Kristi olugbala, eyi ti o gba wa l'aaye lati le se iru ajoyo odun ti oni.....Bi Jesu ba si fa bibo re s'ehin, opo re ni a o se ninu aye yi....Amin!🎄🎄🥁🎻🎺🎷🎵🎶🎸🎄🎄🎺🎷.....
REVIEW CHRISTMAS SPECIAL: REFLECTING ON THE BIRTH OF CHRIST.... 24.12.2022 36:55
Join myself and the crew from last week as we reflect on the birth of our lord and saviour, Jesus Christ. We'll be reading from the gospel according to Luke (parts of) chapters 1&2.....🎄🎺🎷🎵🎶🥁🎻🎸🎄....have a peaceful and joyous celebrations!.....
Atile Bosile/Itile Bosile{¡}...Eto Pataki Fun Odun Keresimesi 18.12.2022 18:52
D'arapo mo wa l'ati ko, ki a si wo awon ohun ti o ro mo ati ile, agbegbe, ipinle, ilu kan bo si omiran nigbati a o ma wo awon eniyan/eekan meji gboogi ti o se be e lati inu bibeli.....🎄🎸🥁🎻🎺🎷🎶🎵🎄......
REFLECTING ON THE ULTIMATE GIFT OF GOD- REVIEW CHRISTMAS SPECIAL 17.12.2022 20:52
Join our guest presenters; Leah Noah and Stephen as we all reflect on the ultimate gift of God this Christmas. 🎄🎄🎶🎵🎷🎺🎻🥁🎸🎄🎄.....Let's share this joy!
Ojukokoro {v} 11.12.2022 20:59
Ni mimu eko yi wa s'opin, e je ki a wo Igbe aye okunrin ti a ti n fe s'oro nipa re; Gehasi, iranse wooli Elisha nigbati a o ka iwe awon oba keji(2 kings 5:20-27).....d'arapo mo wa boya o le ri ohun kan tabi meji ko ninu irin-ajo arakunrin yi👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👩💻👨💻👩💻
Following The King{¡¡} 10.12.2022 24:14
Last week we saw how Jesus explained greatness, ambition and leadership from a new perspective in HIS kingdom. Today, let's look at the life of a man who counted everything he achieved not so much of a thing for the joy of knowing and serving the king, Jesus Christ. This takes us to Phillipians 3:5-8....study with us👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👩💻👩💻
Ojukokoro {¡v} 04.12.2022 20:44
Ni kikase eto nile ni ose ti o koja, awon ibeere kan nilo idahun l'ori igbe aye wooli Elisha. Gbogbo re ni a o si dahun ni okookan loni. Tori be e lo se ye ki o d'arapo mo wa ba wa ko eko yi ..🤔🤔.....👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👩💻
Following The King{¡} 03.12.2022 21:55
As we approach the season of joy and peace(Christmas), let's learn about the one who made it all possible. What kind of king is he? What does he want from his followers, reigning with him in his kingdom?🤔🤔.....👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻
Ojukokoro {¡¡¡} 27.11.2022 19:40
Okunrin kan wa ti a o ko nipa re, sugbon ki a to kan oran re; a gbodo fi idi awon okodoro kan mule ki a le mo ohun ti o fa a ti o fi gbe igbese re naa ti o gbe. Eyi ni yoo mu wa lo ka iwe awon oba keji; ori kaarun(2 Kings 5:1-3, 9-11, 13-16)......👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻
Chatterbox Commune {vi} 26.11.2022 25:56
If you're among the "some" who still asks the question;"how do i know it is God"? That is when God reaches out to you, then you need to grab a seat and study with us.....there are important things to note and consider especially if you have been a chatterbox in your commune with God.....👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻....
Ojukokoro {¡¡} 20.11.2022 18:05
Ni ose ti o koja ni a ri bi ojukokoro ti bere ise ninu aye oba Ahabu ti o ni ola sugbon ti o fe yan Naboti ara Jesreeli je nitori aile mojukuro...1 Kings 21:4-10,14-16....👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👩💻
Chatterbox Commune {v} 19.11.2022 19:37
Today we look at the life of Jesus our champion and ultimate example who though had a very busy ministry schedule BUT never neglected times of solitude and personal worship with the father as we read the gospel according to Mark 1:35-39.....join us and let's study together....👨💻👩💻👨💻👨💻👨💻👨💻👨💻👩💻.....
Ojukokoro{¡} 13.11.2022 18:00
D'arapo mo wa l'ati bere eko titun yi nigba ti a o ko ma wo ohun ti ojukokoro je ati awon apeere l'orisirisii l'ati inu bibeli. Akoko ni a o si ka ninu iwe awon oba kini{1 kings 21:1-4}....ba wa kalo 👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻.....
Chatterbox Commune {¡v} 12.11.2022 19:21
1 Kings 19:11-13 talks about God's communication with Elijah was in a "gentle whisper". Our main focus today is why the gentle whisper? Join us and let's study together 👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻.....
Eri-Okan{¡¡¡}{Eto/Agogo Itaniji Wa} 06.11.2022 23:57
Bi eri-okan ko ba je rere bi a ti wo ni ose ti o koja, iru ipo wo ni o wa/ki ni o sele si? E je ki a ko nipa eri-okan ti o: (¡)dibaje ati eyi ti o;(¡¡)Sokunkun; lati mu eko naa wa si opin lowuro yi.......👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻......
Similar podcasts
Replaio is not a podcast publisher; show names, artwork and audio belong to their authors and are distributed through public RSS feeds.