Review Ministries

Review series Episodes(Review Ministries)

Religion EN ↓ 713 episodes

Having a new life in Christ and taking your relationship with Him one day at a time, to the next level.....Please note: ALL Review Ministries Works ARE NOT MONETIZED! Free to access by allNote: Review Ministries Gives Credit For All Music Played During Every Cast(Which Includes The Writers/Composers, Producers, etc). Thank You For The Labour Of Love.

Author

Review Ministries

Category

Religion

Latest episode

Mar 30, 2025

Where to listen?

Podcasts in the app Replaio Radio Coming soon

Podcasts are coming to the app soon. Install now and be the first to see a whole new take on podcasts

Get it on Google Play Install for free Android 5M+ downloads · 4.8 rating iOS soon

Episodes

Gbiyanju L'ati Fi Adura Şiwaju{¡} 20.08.2023

Luku 18:1...Ninu atotonu/itakoroso mi pelu òpò eniyan ni mo ti s'akiyesi pe; adura je ohun ti a maa s'oro nipa pupo sugbon ti a kii gba bi oro ba doju e tan....awon miiran a gbaa, sugbon won a si tete rewesi. Kini idi re ti o fi ri be e?🤔.....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻..... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com

The Powerful Names Of God {vi}: Jehovah Mephalti(The Lord Our Deliverer) 19.08.2023

Join us as we continue on "the powerful names of God" series. Today we're looking at king Jehoshaphat, who recognised God as the king over the deliverer of his nation as Judah and Jerusalem humbled themselves before the sovereign God.....2 Chronicles 20:1-12....👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻 Contact us on: reviewseries20@gmail.com +447459913053

Ebun Ati Olufunni{¡¡¡} {Wiwawo Kankan Mo Ebun} 23.07.2023

E je ki a mu eko wa wa s'opin l'oni pelu apeere aibikita ati ainaani oloro kan ti o gbagbe wipe: ati ebun, ati ohun, Olorun ni o ni gbogbo re....D'arapo mo wa fun eko ti oni ati ikede pataki l'eyin eko....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻👩‍💻..... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com

The Powerful Names Of God{v}. Yahweh-Yireh Genesis 22:14 22.07.2023

Abraham had a positive attitude towards God's provisions even at the verge of sacrificing his son. Today, we look at another man who had the same attitude. Paul....Phillipians 4:11-13👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍🔬👨‍💻👩‍🔬👨‍💻..... Contact us via: reviewseries20@mail.com

Ebun Ati Olufunni{¡¡} 16.07.2023

Kiki bi o ba ti wa ni apa ibi ififunni ri, a ni ti o je olufunni; ni o le je ki alaye eko tubo ye o ore mi....paapaa nigbati eni naa tabi awon eniyan ti o fi ebun re fun ko ba ka o si, ti won fi oju bintin re tabi foju pa o re🤔🤔.....D'arapo mo wa fun eko ti oni....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻 Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com +7459913053

The Powerful Names Of God {¡v}. Yahweh-Yireh(The Lord Will Provide)-Genesis 22:14 15.07.2023

Today, let's see how our little can become a lot only when we place them in the hands of the lord, when we get him involved in the impossible as we read gospel according to Mark 6:35-44👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻...... You can reach us via email: reviewseries20@gmal.com +7459913053

Ebun Ati Olufunni{¡}...Jakobu 1:17 09.07.2023

Ebun gbigba/ififunni jé aşa ati işe gbogbo orilę ati ede agbaaye pata, o si damil'oju wipe gbogbo wa bayi ni a maa n şe daadaa nibi ebun gbigba. Sugbon ifi ebun funni nko? Bawo lo ti ro pe o n şe ni agbegbe yi🤔? Niwon bi o ti je aşa işedaye, e je ki a wo ibi ti o ti bere tabi olufunni akoko...Genesisi 1:27, 2:7.....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻.... Kan si wa l'ori ęro ayeluja...

The Powerful Names Of God {¡¡¡}. Yahweh Yireh(The Lord Will Provide). Genesis 22:14 08.07.2023

Join us this morning as we look at God's beautiful provision for his servant, Elijah; recorded in 1 Kings 17:8-16....By the way; what is your definition of the word: PROVIDE?🤔....let's study together 👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👨‍💻👨‍💻..... Contact us via email: reviewseries20@gmail.com

Ewu Ife Oro Alumoni (Fun Onigbagbo) 02.07.2023

Ki ba dara bi o ba d'arapo mo wa l'ati jo ko eko yi lati mo awon ohun ti o se pataki tabi je işura ti o ye ki a to jo....kini işura tire?🤔 Matthew 6:19-21 Contact us via email reviewseries20@gmail.com

The Powerful Names Of God {¡¡} El-ROI (The God Who Sees)/Me 01.07.2023

Somewhere in the pages of the bible is the story of a slave woman who got caught up or used for the benefits of her owners but since God is not partial, He showed up to say He sees and cares...study Genesis 21:8-10,14-20 with us this morning 👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻 Contact us via email: reviewseries20@gmail.com

Iran Ti O Mólè kedere {Rírí Koja Ìwòye Ti O L'opin} 25.06.2023

Iwe awon oba keji(2 kings 6:8-17) ni o je ki a l'oye wipe; bi oju ti l'owo nipa ti ara, naa ni o l'owo nipa ti emi. D'arapo mo wa fun eko naa ni kikun....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻...... Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com

The Powerful Names Of God{¡}: El-Roi {The God Who Sees}/Me- Psalm 139:15&16... 24.06.2023

Join us on this new series as we explore and study the different powerful names of God starting from Genesis 16:13&14 where Hagar worshipped God with the name: El-Roi.....for she realised God sees and cares about slaves too....👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻 Contact us via email: reviewseries20@gmail.com

Etan Iborişa{¡¡} {Kini/Tani Orişa Tire}? Isaiah 42:8 18.06.2023

IBORIŞA: Ife si tabi fun awon ohun rere sugbon ti a fi aşeju bò. Bi o ba gbo ti a s'apejuwe iborişa l'ona yi nko, nje kii şe onikaluku wa lo jebi re l'ona kan tabi omiran bayi? E je ki a wo bi iborişa ti ri ni aşa ati işe wa l'oni ati awon ohun ti Olorun nso fun wa nipa re....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻....... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com

Lost{¡v} {The Way/The Path} Proverbs 14:12 17.06.2023

Rounding up this series today, let's look at the way/the path for a moment before going on to still talk about the rich young ruler in Luke 18:18-23. What is God saying to you about your way/path? Are you walking His way?🤔...👨‍💻👨‍💻👩‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻...... Email:reviewministries20@gmail.com

Etan Iborişa{¡}- Isaiah 42:8 11.06.2023

D'arapo mo wa l'ati jo ko eko titun yi paapaa ki a le wo ohun ti orişa/iborişa je ni igba atijo tabi fun awon ara igbaani ati ohun ti o da ninu aşa wa l'oni....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👩‍💻..... Email: reviewseries20@gmail.com

Lost{¡¡¡} {Divided Attention} 10.06.2023

Today, let's look at the story of a man who went to meet Jesus that he may know whether he was on track in his journey of faith but left sorrowful because he had a divided attention. He was religious and yet lost. Come with us on this adventure into the gospel according to Luke 18:18-23..👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👨‍💻👨‍💻👩‍💻.... Email: reviewseries20@gmail.com

Èrù{¡¡¡} {Gbigbe Igbe Aye Igbagbo Pelu Igboya}.....Orin-Dafidi{Psalm 27:1} 04.06.2023

L'ati k'ase eko yi nile, awon apeere meta pataki kan ti a ti ş'eto sile fun eko t'oni. D'arapo mo wa ki a jo wo o ninu oro Olorun 👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻...... Email: reviewseries20@gmail.com

Lost{¡¡} {Distant/Far Away Land} 03.06.2023

Today we look at the story of the lost son and how the father had to longingly watch and patiently wait for him to willingly return home as we read from Luke 15:11-24....👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻 Email: reviewseries20@gmail.com

Eru{¡¡}- Orin-Dafidi 56:3&4 28.05.2023

Ònà wo ni a le s'egun nigbati satani ba ko ipaya ba wa l'ati yi afojusun wa pada kuro ni igbekele ninu Olorun? D'arapo mo wa l'ati wa idahun ninu oro Olorun 👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻......

Lost{¡} {Wanderers}...Matthew 18:12&13 27.05.2023

Checking the meaning or definition of LOST in the dictionary, i discovered a deeper meaning than i personally thought or past the general meaning....why don't you join us and let's study together looking at the physical and spiritual aspects of it starting from the gospel according to Luke 19:1-7,9&10👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻

Èrù {¡} 21.05.2023

Gbiyanju l'ati d'arapo mo wa ni bíbèrè ékò wa titun nipa èrù ki o le ye o iru eyi ti a fe ko nipa 'toripe itumo re pin si ona meji ninu oro Olorun....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👩‍💻

Fire{¡¡¡}🔥🔥🔥{Praise To The God Of The Fire} 20.05.2023

To round up this series, let's finish up reading our text in Daniel 3:28-30 to see how praise came AFTER the fire even from the mouth of stubborn hearted Nebuchadnezzar.....🎵📯🎷🎺....👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👩‍💻.....

Igbagbo Ati Áláá{¡¡¡} {Títèlé Jesu N'iye} 14.05.2023

Ni mimu eko yi wa s'opin, e je ki a wo bi Olugbala ti mura okan awon omo ehin s'ile l'ati kun fun igbagbo tooto lai y'ęsę tori o mo ohun ti o n bo wa şe. Matiu 16:21-23,.....24....Ati pe irin-ajo igbagbo n'iye.....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻.....

Fire{¡¡}🔥🔥{Another In The Fire} 13.05.2023

If and (or) when we face hardship of life/fire in our own strength, we're 99.9% likely to suffer a third degree burn. In other words, we won't make it! Come back with us to the book the book of Daniel 3:24-27 to see how the three young men from Judah got through. Was it easy?🤔...👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻

Igbagbo Ati Àlàá{¡¡}{Igbagbo Kii Se Idan} 07.05.2023

L'oni, e je ki a wo igbe aye Poolu, awon idojuko ati ilakoja re, inunibini ohun ipenija koda l'ehin ti o fi aye re fun Kristi ni bi o ti ş'alaye ni Korinti keji{2 Corin.11:24-28}....irin-ajo igbagbo kii se ti afé tabi idan....👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻👩‍💻👨‍💻.....

Listen to the Review series Episodes(Review Ministries) podcast in Replaio

Radio and podcasts in one app - free, with no sign-up. Install today and do not miss the launch

Get it on Google Play

Replaio is not a podcast publisher; show names, artwork and audio belong to their authors and are distributed through public RSS feeds.